Toyin Agbolade
Adajo Adedokun ti pase pe ki idile Emiolu ati Oshunbiyi lo se suuru nipa oye oba ilu Iresa Adu
Ojo ketalelogun osu kewa yii ni adajo naa soro yii ni kootu Igbon nipinle Oyo.
Won tun ti sun igbejo si ojo kokanla osu kejila odun yii ti ile ejo si ti pase pe ki awon idile Oshunbiyi ye e pe ara won ni Aresa tilu Iresa Adu mo titi ti ile ejo yoo fi kede eniti oba ilu naa to si.
No comments:
Post a Comment