Ileese Adron ti gbe eto'Lemon friday promo' kale,ẹlẹẹkẹsan iru ẹ re e,ti eto yii si ti sọ ọpọ ayalegbe di onile lori.
Nibi eto 'Lemon Friday promo to waye ni ofiisi ADRON to wa nipinlẹ Eko yii ni ọga ileeṣẹ naa,Arabinrin Adenikẹ Ajọbọ ti fi idunnu rẹ han lasiko to n ṣalaye awọn anfaani to wa ninu eto yii.
O salaye pe,jije ebun bii,eran agbo,iresi,ero amule tutu,ero amurungbe,ero amomitutu,ero amohunmaworan,ero afosomo rekete bee lopo ebun miiran wa fun jije
O tesiwaju pe,o le sanwo fun odindi osu merindinlogoji(36months)pelu irorun
Ileese Adrons si ni ile kaakiri ipinle to wa ni orile ede yii bii ipinle Eko,Ogun,Osun,Abuja,Oyo,Niger,Ekiti,Nassarawa,Plateu atawon ipinle miiran.Boya iwo fe mo si i nipa eto'Lemon friday promo' o le kan si ofiisi Adrons to wa ladugbo e nitori ileese yii nikan lo se e fokantan ninu ilẹ ati ile tita.
No comments:
Post a Comment