Inu ibanuje ni Saheed Balogun to je oseretiata okunrin wa lasiko yii pelu bo se padanu akobi re lobinrin,Zeenat Balogun.Opo awon akegbee re ti n ba agba oje oseretiata naa daro
No comments:
Post a Comment