Omooba Aderounmu Kazeem lo n ṣọjọ ibi loni - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Friday, December 27, 2024

Omooba Aderounmu Kazeem lo n ṣọjọ ibi loni


Gbogbo ọjọ kẹtadinlọgbọn oṣu kejila ni ayajọ ọjọ ibi oludasilẹ ileeṣẹ iroyin 'Alore,omooba Aderounmu Kazeem,omo won ni ṢAARẸ OLU.
Agba oje oniroyin ni,ilu Eko lo fi sebugbe.Api baide oga wa daadaa,emi e a sopo odun laye ninu owo,alaafia ati aiku.

No comments:

Post a Comment

Pages