Treasure park and garden phase 2(city of David) treasure park and garden phase 3(Capetown estate).igba keji re e ti ipinle naa yoo gbe osupa o kare lai fun ileese ADRONS nipa fi fun un niwe ase yii
Gomina ana nipinle naa,Senator Ibikunle Amosun naa fun ileese ADRONS niwe C of O lori estate won to wa ni Treasure park and garden phase 1(Genesis estate ati glasshouse estate)lodun die seyin.
Lasiko ti oludasile ileese ADRONS,Aare Adetola Emmanuelking n dupe lowo gomina ipinle lo ti so pe,oun mo riri ipa ti gomina n sa lati mu idagbasoke ba eto ile gbigbe ati idagbasoke ipinle naa.
Bee lo seleri lati tubo je ko di ohun irorun fawon eeyan pe ,won le di onile lori lona irorun pelu ileese ADRONS

No comments:
Post a Comment