Oriire nla,Alaaji Ọlatunde Albert Ọlanrewaju di Oluọmọ Adinni Kutọ Abẹokuta - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Friday, December 13, 2024

Oriire nla,Alaaji Ọlatunde Albert Ọlanrewaju di Oluọmọ Adinni Kutọ Abẹokuta


Awon ololufe baba oloye tuntun nilu Abeokuta ni won ti n ba Alaaji Albert Olatunde Olanrewaju yo ayo pelu bo se di Oluomo Adinni Kuto ni Abeokuta ipinle Ogun
Oriire keji ni pe,baba oloye tuntun tun si ile itura nla kan si adugbo Daleko Idi ori ni Abeokuta,nigbati gbajumo olorin isilaamu nn,Bukola Alayande Ere Asalatu forin dabira

No comments:

Post a Comment

Pages