Oludasilẹ ileeṣẹ Adron,iyẹn ileeṣẹ to n ta ilẹ lọna irọrun fawọn olugbe orilẹ ede yii,Aarẹ Emanuelking Adetola ti fi oro ibanikedun ranse sawon molebi oloogbe oloye(dokita)Adewunmi Oriyomi Onanuga to je Yeye Oba Makun nijebu ipinle Ogun to jade laye lojo die seyin.
Aare Adetola sapejuwe Onorebu Onanuga tawon eeyan mo si 'ijaya' gege bii obinrin akinkanju to tun nife awon eeyan to wa layika e,bee lo n fe itesiwaju fun agbegbe to n soju fun nile ijoba .
O tesiwaju pe,iku re ba opo lojiji sugbon ohun gbogbo ye Olorun aseda wa



No comments:
Post a Comment