Ileeṣẹ ADRON ki gbogbo awọn aṣoju kaabọ si apejọ ọlọdọọdun - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Wednesday, January 15, 2025

Ileeṣẹ ADRON ki gbogbo awọn aṣoju kaabọ si apejọ ọlọdọọdun








Ọjọ kejila oṣu kinni ọdun yii nileeṣẹ ADRONS HOMES AND PROPERTIES gbalejo awọn aṣoju wọn ti o si jẹ pe ,ọsẹ kan gbako ni ipade apejọ yii yoo fi waye ni olu ileeṣẹ wọn to wa nipinlẹ Eko.
Aarẹ Emmanuelking Adetola to je oludasile ati oga agba ileese to se e gbokanle ninu tita ile lona irorun ni olugbalejo agba ti ogbontarigi onisowo ile yii si ki awon to wa nijoko kaabo,o soro lori 'ifiraenijin'bee lo so pe,o dara ki eeyan nife ileese to n ba sise,iwa rere,oyaya sawon onibara ati fifi ife han si won se pataki.
Olori Aderonke Emmanuelking ,naa soro lori awon omo,ara ati mimo pe molebi ni gbogbo awon alabasisepo nileese naa,iyawo oludasile to je oga agba nileese naa wa ro awon osise lati maa fifehan si ara won nitori bi eeyan ba se sise onise lo maa se sise ara e lojo iwaju.

No comments:

Post a Comment

Pages