Api baide tu yuuu Ẹlẹlẹ Mowe. - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Thursday, March 6, 2025

Api baide tu yuuu Ẹlẹlẹ Mowe.


Gbogbo ayajọ ọjọ keje oṣu kẹta ni ọjọ ibi Alaaji Rafiu Ọkanlawọn Oseni,ẹni tọpọ mọ si Anọbi Mowe,Apagunpọtẹ ilu Igbẹin.
Ma a jo sibi to wun ẹ jare,alaanu awọn mẹkunnu,baba oloye rẹpẹtẹ,adura wa ni pe,ẹmi ẹ a ṣọpọ ọdun loke eepẹ ninu alaafia,owo ati ẹmi gigun,api baide tu yuuuu Ẹlẹlẹ Mowe.

No comments:

Post a Comment

Pages