Oludije ípo gomina nipinlẹ Eko, Gbadebo Rhodes Vivor fee joye nla lEkoo - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Thursday, April 10, 2025

Oludije ípo gomina nipinlẹ Eko, Gbadebo Rhodes Vivor fee joye nla lEkoo



Ilu  Badagry yoo mi
 titi lọjọ Abamẹta, Satide to n bọ yii 

Ọjọ   naa ni  Ijọ 'Oloriṣa Parapo Agbaaye' fẹẹ fi gbajugbaja oloṣelu ati oludíje ipo nipinlẹ Eko labẹ ẹgbẹ oṣelu Labour, Gbadebọ Rhodes Vivor joye Ọbalẹfun( Peace Ambassador ) ijọ naa.

Gbọngan Ayapot Hotel and Event Centre to  wa ni  Ado-Odo, niluu Badagry layẹyẹ, naa yoo ti waye.

 Nitori ipa nla ti ọkunrin oloṣelu naa ko fun idagbasoke ati ilọsiwaju awon eeyan lo jẹ kí wọn 
fee foye nla ọhun da a lọla.

Awon eeyan pataki lawujọ ni wọn n reti nibi ayẹyẹ iwuye naa.

No comments:

Post a Comment

Pages