Akarigbo Remo,Oba Babatunde Adewale Ajayi moriri Aare Emanuelking Adetola,Oludasile ileese ADRON eyi lo mu Ori ade sayeye aadota odun fun,Otun Akile Remo laafin re to wa ni Sagamu.
Otun Akile Remo,Aare Adetola dupe lowo Alayeluwa fun ayeye ojo ibi ti Kabiesi se fun oun,bee lo seleri lati ma gbaruku ti ilosiwaju Remo lapapo.
Akarigbo lasiko to n soro so pe,ife ilu ati imudagbasoke Remo ti Aare Adetola ni sawon omo bibi Remo lo mu oun se ayeye naa fun un.
No comments:
Post a Comment