Toyin Agbolade
Gbogbo ayajo ojo karun un,osu karun un ni ayajo ojo ibi Alaaja Salawa Abeni Mordenizer,tawon omo e nidi ise orin bii,Alaaja Ejide,Alaaja Baritide,Iya Oriki atawon mi in si dun iya naa ninu pelu bi won se duro ti i lati ba a ge akara oyinbo ti jije mimu si sele nile e to wa nipinle Eko.
Adura tiwa ni pe,emi yin a sopo odun laye,api baide Mama Okiki




No comments:
Post a Comment