Aarẹ Adetọla EmmanuelKing ṣedaro Aarẹ Ana,Mohammed Buhari to doloogbe - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Thursday, July 17, 2025

Aarẹ Adetọla EmmanuelKing ṣedaro Aarẹ Ana,Mohammed Buhari to doloogbe


Oludasile ileese ADRON iyẹn ileeṣẹ to n ta ilẹ ati ile lọna irọrun fọpọ eeyan,Aarẹ Adetọla Emmanuelking ti sedaro Aare ana ni Orile ede yii,Mohammed Buhari to je ipe Olorun lojo Sannde to koja yii.
Aare Adetola sapejuwe Oloogbe Buhari gege bii adari gidi ati baba rere to feran awon olugbe Orile ede yii lasiko to je Aare.
Oludasile ileese ADRON ko ṣai mẹnuba diẹ ninu awọn aṣeyọri Aarẹ ana lasiko to wa nipo naa,bẹẹ lo gbadura pe,ki Ọlọrun tẹ Aarẹ ana to ti lọ ba ẹlẹda rẹ yii si afẹfẹ rere bẹẹni ko duro tawọn mọlẹbi atawọn olugbe Orilẹ ede yii to fi saye lọ

No comments:

Post a Comment

Pages