Alaaji Aremu Adeniyi gbami eye nla nilu Eko - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Sunday, July 13, 2025

Alaaji Aremu Adeniyi gbami eye nla nilu Eko


Toyin Agbolade
Inu Gbongan nla kan nilu Eko gbalejo awon eeyan pataki lawujo lasiko ti gbajumo oniroyin ayelujara ati puromota awon olorin fuji ati takasufe ,Alaaji Aremu Adeniyi eniti awon ololufe e mo si Arems gbami eye nla.
Image Mindset Global Award mo riri ise takuntakun ti Alaaji Arems se lawujo awon olorin,to si je pe,oun lami eye naa to si.
Arems lasiko to n ba wa soro so pe,oun dupe lowo awon ololufe oun ati akeegbe oun bee lo dupe lowo Oba Orin Osupa Saheed lona to yato.
'Modupe lowo Oba Orin ateyin afenifere fun aduroti yin,ti mo si fi ami eye yii sori gbogbo yin kaakiri agbaye'

No comments:

Post a Comment

Pages