Toyin Agbọlade
Ọga agba ati Oludasilẹ ileeṣẹ ADRONS,Aarẹ Emmanuelking Adetọla wa lara awọn oniṣowo ile to ṣepade ninu ọgba ileewe yunfasiti ipinlẹ Eko lati wa ojutu si ọrọ ile to ndawo tọpọ ẹmi si n ba awọn iṣẹlẹ naa lọ.
Purofeso Lekan Oduwaye ti eka eko to nkọ nipa imọ ile kikọ(urban and regional planning DURP) atopo awon onisowo ile lo wa nikale lojo naa.
Aare Adetola so pe,iwa ole,ojukokoro ati aisooto lo n mu opo ile wo pale lojiji,opo agbasese ki n ra ohun elo ikole to dara nitori owo ti won fe ji sapo ara won,ti eroja ikole ko ba duro daadaa o le je ki ile wo pale lojiji.
Dokita Idris Salako so pe,aigba awon iwe to peye to le se amona enito n kole le faa ki ile tete wo,komisona nipa eto ikole nipinle Eko ti wa so pe,kawon ijoba maa mojuto ile ti awon eeyan nko nipinle naa.
TpL Tunji Odunlami(FNITP)Purofeso Ayo Omotayo lati ipinle Ogun,Purofeso Modupe Omirin,Dokita Taofik ati Dokita S.A Adeyemi naa wa nikalẹ lọjọ naa.
No comments:
Post a Comment