Alhaji Aremu Adeniyi lo n sojo ibi loni - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Tuesday, August 26, 2025

Alhaji Aremu Adeniyi lo n sojo ibi loni

Api baide tu yuuuu,Alaaji Aremu Adeniyi,Alaga ati oludari ileese Arems entertainment ati telifisan 1stEleven Naija,manija Alaaji Abass Obesere,bee lo je eeyan Alaaji Saheed Osupa ObaOrin.
Gbogbo ayajo ojo ketadinlogbon osu kejo ni ayeye ojo ibi re,omo Ibadan nile oluyole,puromota to moye ni pelu,maa jo sibi to wun e jare,emi e a sopo odun laye.

No comments:

Post a Comment

Pages