Awon Molebi Olorin sakara nni,Alaaji Wasiu Ejire Olofin sadura odun merindinlogun to jade laye - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

I

Tuesday, August 19, 2025

Awon Molebi Olorin sakara nni,Alaaji Wasiu Ejire Olofin sadura odun merindinlogun to jade laye

Ilu Sango Ota nipinle Ogun lawon ebi,omo,iyawo,omo omo,ojulumo ti pejo lana ojo aje lati sadura odun merindinlogun ti agba oje olorin sakara,Alaaji Wasiu Ejire Olofin jade laye.
Omo oloogbe toun naa n korin sakara,Alaaji Oganla dupe lojo naa lowo awon ore ati ololufe e fun aduroti won latigba ti baba ti je ipe Olorun nigbati iyawo baba naa dupe lowo awon olorin fuji bii,Alaaji Sefiu Alao,Wasiu Ayinde,Saheed Osupa,Pasuma fun ife ti won fi han si i leyin iku baba naa.

No comments:

Post a Comment

Pages