Iku doro,o mu kanselo yii lo leyin ose meji to bere ise - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

I

Wednesday, August 13, 2025

Iku doro,o mu kanselo yii lo leyin ose meji to bere ise

Oluwakemi Rufai niku ti mu lo nijoba ibile Ibeju,oun nikan lobinrin laarin awon kanselo agbegbe naa.
Aisan ranpe la gbo pe o se e,gege bi Alaga ijoba ibile naa,Sesan Olowa se kede e

No comments:

Post a Comment

Pages