O mase o,oseretiata meji ku laarin ojo meji si ara won - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Saturday, August 2, 2025

O mase o,oseretiata meji ku laarin ojo meji si ara won

Omotola Odunsi to se fiimu Amonata ati Odunayo Olufemi Oloto to se baba oko Regina Chukwu ninu fiimu Ọlẹ ti jẹ ipe Ọlọrun lọjọ weside ati tọside to kọja yii,a fi ki Ọlọrun ba wa dawọ iku ojiji duro laarin awọn Oṣeretiata lasiko yii

No comments:

Post a Comment

Pages