Oludasile ileese ADRONS ṣedaro Awujalẹ to waja - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

I

Sunday, August 3, 2025

Oludasile ileese ADRONS ṣedaro Awujalẹ to waja


Toyin Agbọlade
Oludasilẹ ileeṣẹ ADRON iyẹn ileeṣẹ to ṣe e fọkantan ninu ilẹ ati ile rira laisi wahala,Aarẹ Adetọla Emmanuelking ti sedaro,Awujale Ijebu Ode,Oba Sikiru Adetona to waja lojo sande to koja yii.
Aare Adetola sapejuwe Ori ade bii baba rere ati Oba gidi lasiko to wa lori apere awon baba re,bee lo so pe,odindi odun marunlelogota ti kabiesi fi wa lori ipo gege bii Awujale ijebu mu opo idagbasoke ba gbogbo ijebu lapapo.

No comments:

Post a Comment

Pages