Aare Adetola KoF tun gbosuba kare lai fawon afobaje pelu bi won se yan eni to to,to tun ye sipo ti Odemo tuntun si ti n ba awon eto lo gege bii ilana ifobaje ilu naa.
Aare Adetola EmmanuelKing,oludasile ileese ADRON iyen ileese to nta ile lona irorun fawon onibara won ti ki Oba tuntun ni Isara Remo,Aare Adetola to je Otun Ashiwaju ilu Remo ki Odemo tuntun,Bashorun Oluwole Ogunbayo fun ti oriire gege bii Odemo tuntun nilu naa.
No comments:
Post a Comment