Aafin Oba Ogunwusi Enitan Ojaja keji ni awon Oga Oga lati ileese Adron iyen ileese to se e fokantan nipa ile tita ati rira ti soro yii lasiko ti won lo seleri fun Ori Ade pe,awon yoo gbaruku ti odun olojo todun yii gege bii ise won.
Arabinrin Adenike Ajobo lo soju oludasile ileese Adron lojo naa ,to si so pe,odun olojo je odun to ma n gbe isese,asa ile Yoruba ga kaakiri agbaye idi eyi ni ileese Adron se tun setan lati gbaruku ti odun olojo todun yii.
No comments:
Post a Comment