Lasiko ti odun keresi ati odun tuntun ti n sunmo etile yii,iwo naa le di onile lori pelu owo ti ko gara nitori aye wa lati sanwo diedie.
Owo akoko ti o dara lati san ni,#50,000 leyin eyi o le san eyi to ku diedie,ileese naa ni ile si Abuja,Eko,Oyo,Ogun ,ipinle Nassarawa,Ekiti atawon ipinle mi in.
Iye ile ti o ba ra ni iye ebun odun ti o maa je,ebun bii,apo iresi,Adiye,ororo,ero amunawa,ero amohunmaworan,ero amuletutu,gaari,epo,eran agbo lo wa gege bii ebun fawon to ba ra ile nileese Adron.
Osu keje si osu kokanla le maa fi sanwo diedie,to si je pe,ojo kefa osu kinni odun to n bo ni puromo yoo pari.
No comments:
Post a Comment