Ayeye odun olokun ati odun Aje ti Yeye Ajesikemi Omolara Olatunji todun yii larinrin - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Monday, October 6, 2025

Ayeye odun olokun ati odun Aje ti Yeye Ajesikemi Omolara Olatunji todun yii larinrin

Oba Orin Saheed Osupa Akorede lo dalubole lojo ti Yeye Ajesikemi Omolara sodun aje ati odun olokun nilu Eko.
Yeye Ajesikemi dupe lowo awon ololufe e kaakiri bee lo sadura pe,emi gbogbo wa a sopo odun laye

No comments:

Post a Comment

Pages