Egbon Ṣẹfiu Alao di baalẹ Abule Lufoko nijọba ibilẹ Ọbafẹmi Owode - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Lemon Friday

Lemon Friday
Lemon Friday

Thursday, October 9, 2025

Egbon Ṣẹfiu Alao di baalẹ Abule Lufoko nijọba ibilẹ Ọbafẹmi Owode

Alaaji Samsodeen Adekunle iyẹn ẹgbọn gbajumọ olorin fuji nni,Alaaji Ṣẹfiu Alao Baba Oko ti di baalẹ abule Lufoko Oyomo nijọba ibile Ọbafẹmi Owode.
Alaaji Adekunle to ti jẹ ọpọ oye nilu Ọba,ẹgbọn Alao ni Jagunọdẹ ilu Ọba,Oṣupa adinni ilu Ọba ati Akogun ilu Ọba ti oye baalẹ ilu Lufoko si ti kan an ti idaniloju si wa pe,eto ti n lọ labẹlẹ pe ilu naa yoo di ilu to ni ọba lori laipẹ,to tumọ si pe,ẹgbọn Ṣẹfiu Alao ni yoo di ọba ilu naa.
Awọn ololufẹ Agbara orin ti n ki i ku oriire lasiko yii.

No comments:

Post a Comment

Pages