Ọga agba ileeṣẹ iwe iroyin Gbelegbo nilo miliọọnu Marun-un lati fi ṣiṣẹ abẹ - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Saturday, November 15, 2025

Ọga agba ileeṣẹ iwe iroyin Gbelegbo nilo miliọọnu Marun-un lati fi ṣiṣẹ abẹ

Odu ni Ọgbẹni Ṣina Fadare laarin awon agba oje akoroyin lorile ede yii,oun ni Olotu iwe iroyin gbelegbo tileese THE NATION n gbe jade lede yoruba.
Sugbon lasiko yii ni aisan kan toruko re n je(cervical spondylosis)da okan ninu awon oga nillese Aare Orile ede yii,Bola Ahmed Tinubu gule ,tawon molebi Ogbeni Fadare si ti n rawo ebe sawon alaanu,oninuure kaakiri Orile ede yii.
Milioonu marun un ni Olotu iwe iroyin gbelegbo to je okan ninu iwe iroyin to n jade lati ileese Vintage to je ti Aare Tinubu ti ofiisi won wa ni Fatai Atere,Matori nipinle Eko niilo lasiko yii.
Aarin ose meji nise abe yii gbodo waye ki alaafia le tete je ti Olotu Fadare,ebe lawon molebi Fadare n be eyin eleyinju aanu lati nawo iranlowo si baba yii.
Akanti ti e le fi owo ranse si ni,Oyesina Fadare
Gtb bank
Acct: 0017488881
E seun gan an ni,a o ni fi aisan logba.

No comments:

Post a Comment

Pages