Ki ifẹ le wa laarin awọn Ọba Alade nilẹ Yoruba,Agbaakin Baṣọrun Oloye Muraina Olanshile sepade pelu Olowu tilu Owu kingdom - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Tuesday, January 20, 2026

Ki ifẹ le wa laarin awọn Ọba Alade nilẹ Yoruba,Agbaakin Baṣọrun Oloye Muraina Olanshile sepade pelu Olowu tilu Owu kingdom

Oba Dokita Saka Adelola Matemilola Oluyalo Otileta VII,Olowu tilu Owu Abeokuta gbalejo Basorun Agbaakin ile Yoruba,Oloye Muraina Olanshile ati Olowode tilu Owode Egba ,Oba Kolawole Aremu Sowemimo ,ti won si jiroro lori bi ife yoo se joba laarin awon oba Alade nile Kaaro-o-jiire
Toyin Agbolade
0803579212

No comments:

Post a Comment

Pages