Koko inu iwe iroyin 'Toyin Alariya Online News - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo

Thursday, January 29, 2026

Koko inu iwe iroyin 'Toyin Alariya Online News

Iyawo Alaafin Oyo,Oba Owoade fawon Baale je
*Agba oje Oseretiata yii niilo iranlowo
*Ejo sa Oga ileewe kan ni Abuja je
*Won ti sinku Omije Ojumi gbajumo Olorin Emi
*Won ni Ariyike n sere egele pelu Antar Laniyan,ode ariya ti Saheed Osupa se lodun to koja ni asiri ti tu
*Agbaakin Basorun ile Yoruba sabewo si Oloye Obasanjo
*Eemo iyawo gun oko e pa,nitori asiri tu pe,oko lo bi omo odo won
*Adrons!Ileese to n ta ile ati ilẹ lọna irọrun

No comments:

Post a Comment

Pages