O wa so pawon dokita ti salaye pe,pelu ise abe ti owo re yoo to milioonu kan,omo naa yoo dide rin bee lawon ese ati orun re ti ko duro yoo pada bo sipo.
Eyin abiamo aye ati eyin eleyinju aanu e jowo e ran Temitope lowo pelu iyekiye ti e ba ni,Olorun ki yoo gbe isoro to ga ju emi yin lo pade yin (Amin)
Akanti number:0109532177 Access bank,Sukurat Temitope Oluwa
Phone nomba:09033463049
No comments:
Post a Comment