Alhaji Adewale Badmus joye nla nilu Ogbomosho - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo

Wednesday, February 18, 2026

Alhaji Adewale Badmus joye nla nilu Ogbomosho

Laipe yii ni Oludari ati Alase ileese Alhatyq iyen ileese to se e fokan tan ninu ka ko awon eeyan lo si Meka ati Umurrah lona irorun joye nla nilu Ogbomosho
Otunba Onimolete tilu Molete ni Alaaji Adewale Badmus eni topo tun mo si'Wale Ticket je,tawon ololufe e si ba a de ilu naa lati ba a sajoyo.
Adura wa fun baba oloye tuntun ni pe,oye a mori lase Olorun

No comments:

Post a Comment

Pages