Ara ọtọ ni Ayẹyẹ ọjọ ibi Wolii agbaye nni,Primate Elijah Babatunde Ayọdele tọdun yii - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Saturday, February 14, 2026

Ara ọtọ ni Ayẹyẹ ọjọ ibi Wolii agbaye nni,Primate Elijah Babatunde Ayọdele tọdun yii

Primate Ayọdele Elijah ,oludasilẹ ijọ INRI kaakiri agbaye tun ti ṣe bẹbẹ loni in ọjọ falẹntain to jẹ ọjọ ibi ẹ
Ọpọ ẹbun owo nla,ẹrọ amohunmaworan,ẹrọ amọmitutu,maṣiini iranṣọ,bẹẹdi ibusun,aṣọ,onjẹ lọpọ awọn eeyan gbe lọ sile,ọpọ gbe gaasi idana,ẹrọ to n fọṣọ mọ tonitoni lawọn kan tun gbe lọ sile,bẹẹ lawọn meji tun jẹ ẹbun ọkọ ayọkẹlẹ ni eyi ti ko si iranṣẹ Ọlọrun kankan ni Orilẹ ede yii to ṣe iru bẹbẹ ti Primate Ayọdele ṣe yii ri ninu itan
O tun kọ moṣalaṣi nla fawọn musulumi,iyalẹnu leyin jẹ,tọpọ awọn Ọba Alade,awon Aafa nlanla atawon agbaagba oloselu si wa nijoko lojo falentain ti n se ayajo ojo ibi woli nla naa
Iyaloja General omo Aare Orile ede yii naa ran awon asoju wa,topo awon arugbo,opo si lo sile pelu ebun ati owo tabua

No comments:

Post a Comment

Pages