Asiri tu!Won ni Antar Laniyan n sere egele pelu Ariyike Adeyanju,ode ere odun ti Saheed Osupa se ni odun to koja lopo awon eeyan ti ri won,aso kanna an ni awon mejeeji wo
*Alaaja Sheri Barry Wonder so pe,oun mu Saheed Osupa mo opo eeyan sugbon ko ranti oun mo,o si je edun okan foun.
*Oludasile ileese ADRON ki gomina ipinle,Ogun,Oyo ati Ondo
* Ija nbo laarin Kunle Afolayan ati Funke Akindele nitori fiimu ni o
*Won ti sinku Omije Ojumi gbajumo olorin emi,ni baba awon omo e ba tu opo asiri
No comments:
Post a Comment