Koko iroyin ninu iwe iroyin'Toyin Alariya online news t'ọsẹ yii - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Monday, February 9, 2026

Koko iroyin ninu iwe iroyin'Toyin Alariya online news t'ọsẹ yii

*Kayeefi nla nilu Eko'Awon olorin emi meta ati oniroyin ayelujara kan ku sinu yaara ipo orin po(studio)nilu Eko
*Ipinle Ogun pe Aadota odun,,Sefiu Alao ki Gomina Dapo Abiodun,ni Baba Oko ba n jaye Oba ni Orile ede Canada lasiko yii
*Primate Elijah Ayodele ti so asotele nipa ifemisofo to waye ni Benue
*Oriire nla Saheed Osupa joye nla ni Orile ede Kutonu
*Ija Olasco film ati Okunnu,Olasco je mi lowo-Okunnu
Iro ni alaimoore ni Okunnu,iro lo pa mo mi-Olasco
*Okemesi gbajumo oseretiata niilo iranlowo leyin aisan nla to se e
*Ijamba oko gbemi eeyan meta ni Sango Ota
*Wasiu Ayinde binu somo ise e lode Ariya
Ariwo ko ma daran si oun lorun lo n pa

No comments:

Post a Comment

Pages