Api Baide Baba Oko - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Tuesday, March 24, 2026

Api Baide Baba Oko

Gbogbo ayajo ojo kerinlelogun osu keta ni ayajo ojo ibi agba oje olorin fuji nni,Alaaji Sefiu Alao Adekunle topo mo si Baba Oko,opo awon ololufe Agbara orin ni won ti n ki i kaakiri agbaye
Adura wa ni pe,emi yin a sopo odun laye,eni iyi,eni eye,api baide tu yuuu sir.

No comments:

Post a Comment

Pages