*Oseretiata okunrin toruko e n je'Femi Adewole ti pariwo sita pe,oun ko fun Oloogbe Ajara Lasisi loyun o,awon mejeeji kan jo ma n se fiimu papo ni.
*Aburo Gomina ana nipinle Ogun ,Alaaji Oyesiku Amosun je ipe Olorun nilu Abeokuta leyin to siwaju awon eeyan kirun tan niku mu u lo
*Alaaji Olaide Okadigbo eleyinju aanu nilu Agege nipinle Eko se waasi Ramadan,o seto adura nla fun Aare Bola Tinubu ati Iyaloja General Folasade Tinubu Ojo,opo awon eeyan je ebun ile,meka beeni won ko onje bii iresi,gaari,ororo lo sile lojo naa
*Ija Iran ati America lo fa ijakule ti Saheed Osupa ati Wasiu Alabi ko fi le gba Orile ede America ti won wa lasiko yii lo si Umurrah o
*Ile ejo ti da Daniya lare pe,ko ba omo e lajosepo o sugbon awon aburo iyawo e ti ji iwe ile e gbe pamo lasiko to wa lahamo,lawon molebi ba so pe,iro ni Duniya n pa o
*Ileese Alhatyq ti se Umurrah odun yii,opo awon onibara e ni won n gbe osuba sadankata fun ileese naa
No comments:
Post a Comment