Opo awon ara agbegbe naa so pe,iwa ijomoluabi,irele ati iteriba ti odomode oloselu to jafafa ni naa lo fe mu awon dibo fun un,Onorebu Afeez ki n gberaga beeni ki n ko awon godogodo seyin lati maa deruba awon eeyan yala to ba n jade tabi wa lode ariya.
O tumo si pe,awon olugbe ilu e yoo tete ri i lasiko to ba de ipo .Yato sawon to je pe,opo igba ni awon godogodo won ma n deruba tomode tagba lai ti i de ipo rara.
Sa o,iwa irele ti Onorebu Afeez ni yii la gbo pe,awon olugbe Mokoloki fi setan lati gbe e wole sipo ile igbimo asofin ipinle Ogun lati Mokoloki.
Agbolade Oluwatoyin
No comments:
Post a Comment