Koko iroyin inu iwe iroyin'Toyin Alariya online news' - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Monday, March 2, 2026

Koko iroyin inu iwe iroyin'Toyin Alariya online news'

O mase o!Taiwo Adegbodu,okan ninu ibeji Adegbodu to n korin emi ku lojiji leyin aisan ose meji pere,awon ololufe,molebi n sedaro olorin emi naa.
*Jamal omo Shanko Rasidi to n korin fuji ku lojiji nilu Eko,sugbon nise ni iya omo yii so pe,Shanko ko toju oun atawon omo naa koda o ti fibon hale mo oun ri.
*Egbeda nilu Eko ni David Elijah omo odun mokanla ti jabo lasiko onje(break time)lati oke nileewe ,won ni akegbe e kan lo ti i latoke.omo
*Leyin to di oga agba ileese olopaa orile ede yii,Aare Tinubu so pe,ki Tunji Disu wa ojutu si eto oro aabo orile ede yii.
*Aare Orile ede kan yoo ku lodun yii si odun to n bo-Primate Ayodele oludasile ijo INRI lo so asotele nla yii
*Ni ilorin,okunrin to gbe asewo lo sile itura jona mo inu oteeli ninu aawe
*Ileese Alhatyq nikan nileese to se e fokan tan nipa ka lo si Umurrah ati Meka lona irorun.

No comments:

Post a Comment

Pages