*Emmanuella Ropo iyawo Wasiu Ayinde tele di Seriki iyalode ile Egba,lawon ololufe e ba ba sajoyo.
*Awon ajinigbe tun ya wo soosi kan ni Kwara,eeyan mejo lo ji gbe sugbon meta ti gba itusile lasiko ta a ko iroyin yii tan.
*Baba Ijesha ti soro o,o so pe,won paro mo oun lojosi ni,oun ko fipa bomo kankan lo po.
*Leyin odun kerin in iku Alao Akala asiri ohun ini e tu sita,awon omo ati molebi ti n ja si ogun e
*Oludasile ileese Alhatyq,Alaaji Wale Badmus ki Olora tilu Ora tuntun,Oba Rilwan Yekini Cooler ku oriire,bee lo gbadura pe,asiko re yoo tu awon omo ilu Ora lara.
*Toyosi Adesanya bimo obinrin leyin opo odun sugbon won ba a bi i ni.
No comments:
Post a Comment