*Ni Iselu nilu Owo nipinle Ondo,Aafa Kazeem pa Caroline danu pelu ibinu,ọra(nylon )lo fa ija
*Basit Busari amugbalegbe Saheed Osupa ti di oloselu ,ni Sekinat iyawo Abass Obesere naa ba gbegba oselu nipinle Oyo
*Sunday Igboho ti so pe,Aare Tinubu loun n ba lo o,bee lo ti darapo mo egbe oselu APC
*Omoluabi ni Oonirisa bee lori Ade je oniwa tutu-Basorun Agbaakin ile Yoruba Oloye Muraina Olanshile lo so bee
*Iresi aadota apo ni Aare Bola Tinubu fun wa lati fawon alaini lasiko Aawe yii-Sheikh Ahmad Alfullany Olanrewaju dupe lowo Aare Orile ede yii
**Haaa!awon toogi yawo ile Onorebu Gbolarumi Hazeem igbakeji gomina tele nipinle Oyo,opo dukai ni won ba je
No comments:
Post a Comment