Koko iroyin inu iwe iroyin'Toyin Alariya online News' - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Thursday, April 30, 2026

Koko iroyin inu iwe iroyin'Toyin Alariya online News'

Nitori orin Goke Bajowa ti Boye Best ko,okunrin naa n  binu gidigidi o,lawon ololufe Boye ba so pe,ki o lo be okunrin naa.
*Alfa Suna ti pada be Saheed Osupa atawon ebi Olufimo,ni Saheed Shittu ba fe fi olopaa gbe e,esun pe o ti se oun naa ri ni Shittu fi kan.
*Hon Okadigbo fe dupo sile igbimo asofin kekere ni Agege
*Sefiu Alao,Wasiu Alabi Pasuma ati Adio Atawewe korin nipinle Ogun,Olamilekan Yayi ni won korin fun.
*Taye Currency ti fi olopaa gbe Rolex Dee o,esun ibanilorukoje lo fi kan an,Iyaganku nilu Ibadan lo wa bayii

No comments:

Post a Comment

Pages