Koko iroyin ninu iwe iroyin'Toyin Alariya online news' - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Monday, April 13, 2026

Koko iroyin ninu iwe iroyin'Toyin Alariya online news'

Aafa Suna ti pariwo pe,Saheed Osupa ati Sheik Amiolohun n lepa emi oun,beeni Osupa ko fun oun lowo ise ti oun se fun un bee lo so fawon eeyan ki won ma saanu oun o,Saheed Shittu atopo awon ololufe Osupa ti n so pe,ko ye ki Aafa Suna fi oro asiri toun ati Osupa so sori ero ayelujara.
*Sokoti agba oje onitiata so pe,esin musulumi ko dara o,lawon musulumi ba koju ija si i
*Kunle Afod sabewo sodo gbajumo agba oje oseretiata nni,Kola Oyewo lawon eeyan ba n sadura fun un
*Oloye Opeifa Toriola si ileese tuntun ,ose aworo,bisabisa,aanu,agbo iba ati jedijedi atawon ose lo n ta nibe.
*Nipinle Ogun,awon mejidinlaadota lo wo gau,won da ile soju ona ni.
*Ikunle abiamo o!awon agbebon pa ode asogbo marun un ni Kwara.
*Iyawo Portable Harejan onitiata figbe bonu o,o so pe ki Lizzy Anjorin ma sepe fawon omo oun mo o

No comments:

Post a Comment

Pages