Koko iroyin inu 'iwe iroyin Toyin Alariya online news' - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Monday, May 11, 2026

Koko iroyin inu 'iwe iroyin Toyin Alariya online news'

Lanre Teriba Atorise lo korin nibi ayeye ikomojade Were olorin iyen Portable,Fijabi loruko omo naa.
*Ileese Alhatyq n ko awon onibara e lo si hadji odun yii ninu osu kejo,iwo naa le ba won sise hadji.
*Awon ololufe Taye Currency ati Wasiu Alabi Pasuma sepade nla nilu Ibadan,lati fi opin si ija aarin awon olorin naa.
*Okiki Bright ssabewo sodo Oluaye fuji,ni Wasiu Ayinde ba dupe lowo Shina Akanni fun ipa to ko laye Okiki Bright.
*Ileese Al-Yusuf sedanileko fawon onibara e to n ko lo si hadji odun yii nilu Eko.
*Oba Esa oke ati Ologudu nilu Eko waja laarin ojo die sira.
**Imaam agba ile Yewa ku ,won ti sinku e nilana esin isilaamu.
*Ayoka omo Ologede sayeye meta nilu Eko,o sile tuntun,o sodun awon ọkọla,bee lo sayeye ojo ibi lawon ololufe e ba ba a dupe lowo Olorun.
****Fun ipolowo oja ,e pe nomba yii,08035792122

No comments:

Post a Comment

Pages