Sefiu Alao wa nilu Amerika bayii,sugbon yoo de laipe yii lati sere odun fawon ololufe e lojo keji odun ileya,milioonu kan ni tebu aga ijoko mewa,ilaji miliionu fun aga ijoko marun un,ati fila lowo perente fawon to ba fe e wole sinu gbongan naa.
*Wasiu Ayinde ra eran agbo meji fun Alaaji Kollington Ayinla bee lo fun un lowo gidi lati fi sodun ileya,ni Baba nkebe ba sadura fun Oluaye.
*Iya Kemi Korede onitiata jade laye o,leyin osu die ti egbon Kemi ku.
*Sunday Igboho sedasile egbe'iru ekun'o so pe ,ona lati daabobo ile Yoruba ni.
*Oba Adebanji Ajibade Alabi Afuntade akoko Alawe tilu Ilawe Ekiti ti jade laye.
No comments:
Post a Comment