Koko iroyin tinu iwe iroyin'Toyin Alariya online news'tose yii re e - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Monday, May 18, 2026

Koko iroyin tinu iwe iroyin'Toyin Alariya online news'tose yii re e

Nitori iforowero ti Sefiu Alao se,lo mu awon ololufe Osupa ati Abass Akande maa soro lasiko yii,Sefiu so pe ,Aburo oun ni Saheed Osupa sugbon ore oun ni Wasiu Alabi Pasuma beeni Obesere ko dasi oro egbe onifuji eleni meje tawon da sile lo mu awon yo oruko e kuro,ohun ti Agbara orin so re e tawon ololufe olorin mejeeji yii fi fariga sugbon gele mawobe ni Baba Oko we si won.
**Ileese Apase ti Alaaji Ismail ti si ofiisi tuntun si ipinle Eko,won n ta ile ati ilẹ ni wọn n ta bẹẹni wọn nilẹ kaakiri orilẹ ede yii.
*Oluso Faleyinmu ti so pe,sokisoki lateyin pelu obinrin le fa aisan roparose o.
*Alaaji Sk Sensation lo tun wole fun saa keta gege bii Aare egbe onifuji kaakiri agbaye.
*Gomina Seyi Makinde tipinle Oyo fe dupo Aare Orile ede Naijiria o.
*Tutuye onifuji fe sayeye nla nipinle Eko,Scopido Ogolorinwa lo maa korin nibe.

No comments:

Post a Comment

Pages