Ómó wón nile Alade Oke-Ayegun ni Isanlu-Isin .
Isanlu iyeye omo ajokogun,E sin mi ka lo pagba sanlu ,Eni moki reree momu n peji,,Mo pojo kojo aro sunsun,ojo agba kero lasan,Bo ba peru,apa omo,Omo jagunjagun,Omo ajagunla,Omo ajagun mo ngbesogun,Omo alogunlalobo,Omo akeru wale.
Lagbara Olorun Emi é a sopọ odun laye ninu owo, àlàáfíà àti ìlera pípé
No comments:
Post a Comment