Gbogbo ogbon ojo ninu osu kẹsan -an ni ayajọ ojo ibi agba oje olorin isilaamu nní,iyen Alaaja Hafsat Sideeq,adura tiwa ni pe,emi yin a sopọ odun ninu alaafia ati ifọkanbalẹ.Api baide tu yuuu eni iyi eni eye
Wednesday, September 30, 2026
Home
Unlabelled
Alaaja Hafsat Sideeq lo n sojo ibi loni in
Alaaja Hafsat Sideeq lo n sojo ibi loni in
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
Author Details
Iroyin Tojubọle jẹ iroyin ori ayelujara to n kọ nipa awọn ohun to n lọ lagbegbe wa, yala l'agbo amuludun, iyẹn awọn oṣere; iṣẹlẹ kayeefi; eto oṣelu ati iṣejọba pẹlu oniruuru ẹka iroyin kaakiri agbaye.
No comments:
Post a Comment