Oriire nla,Alaaji Wale Badmus oludasile ati adari ileese Alhatyq iyen ileese to nko awon eeyan lo sí Mékà ati Umurrah lọnà irorun fe sayeye ojo ibi Àádọta odun laye - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

Adron Promo

Adron Promo
https://blog.adronhomes.com/promotional/

Sunday, September 13, 2026

Oriire nla,Alaaji Wale Badmus oludasile ati adari ileese Alhatyq iyen ileese to nko awon eeyan lo sí Mékà ati Umurrah lọnà irorun fe sayeye ojo ibi Àádọta odun laye

Eto ati ipalemo ti nlọ lọwọ tawon ololufe Alaaji Adéwálé Badmus eni tawon ti e mo sí Alhatyq pẹlu bi ayeye ojo ibi Àádọta odun e yóò se waye nilu Eko losu to n bo
Alaaji Wasiu Alabi Pasuma ni yóò sere fawon alejo lojo naa,gbajumo Sorosoro ori redio nní, Ifankaleluya ati Lateef Adedimeji to je oṣeretiata ni won yóò dárí ayeye,Aso tiye re je egberun lọnà aadojo  [150,000] láwọn èèyàn yóò ràn lati fi wole lojo naa

No comments:

Post a Comment

Pages