Ore mi timotimo ni Pasuma - Atawewe - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Tuesday, October 6, 2020

Ore mi timotimo ni Pasuma - Atawewe


Ilu mo on ka osere fuji nni, Alaaji Sulaimon Adio Atawewe ti so pe ore kan soso ti oun ni laarin awon osere fuji ni Alaaji Wasiu Adekunle Ajibola Pasuma.

Atawewe tawon ololufe e tun mo si Etu Fuji tabi Baba Oloye so pe osere fuji ti oro oun atie ye ara won daadaa ni Oga Nla fuji.

'Loooto loooto ni mo wi fun yin, ore mi ni Pasuma, mo feran e, oun naa si feran mi daadaa'. Mr. Ronaldo lo soro yii.




No comments:

Post a Comment

Pages