O mase o! Adajo ti pase pe ki wolii Sotitibire lo gbadun igbesi aye e to ku l'ogba ewon - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Tuesday, October 6, 2020

O mase o! Adajo ti pase pe ki wolii Sotitibire lo gbadun igbesi aye e to ku l'ogba ewon


Loni ojo kefa osu kewa gan an ni adajo Odusola ti Ile ejo giga kan nilu Akure ti pase pe ki Wolii Babatunde to je oludasile ijo Sotitobire to wa nilu Akure lo gbategun ati pe ki Wolii Olorun naa lo gbadun igbesi aye re to ku l'ogba ewon.

Odun to koja ni omo odun kan toruko re n je Gold Kolawole s'onu lasiko isin ni soosi Wolii Babatunde,ti a si pada gbo pe ilukulu ni awon alagba soosi yii na n iya Gold nigba naa.

Ohun ti a gbo ni wipe aikobi ara so Oro omo to sonu yii wa ninu ohun to je ki Oro naa le to bee.

Ti e o ba gbagbe pe o ti pe die ti igbejo naa ti bere nibi ti won ti fesun kan Wolii Babatunde atawon mefa miran pe won mo nipa bii omo odun kan to n je Gold se Sonu sugbon ti adajo ti pada dajo ewon gbere fun Wolii naa.

No comments:

Post a Comment

Pages