O sele Obabinrin sorosoro ti da ile-ise asaraloge sile s'igboro ilu Eko - TOYIN ALARIYA ONLINE NEWS

Iroyin Yajoyajo

ILEYA TI DE

ILEYA TI DE
ILEYA TI DE

Tuesday, October 6, 2020

O sele Obabinrin sorosoro ti da ile-ise asaraloge sile s'igboro ilu Eko

Odu ni yeye Abidemi Olukuewu je laarin awon sorosoro Lori redio ati telifison,omo bibi ilu Abeokura nipinle Ogun yii je okan pataki laarin awon sorosoro ti o si n se daadaa' nidi ise naa lasiko yii.

Iroyin ayo ti a gbo nipa Yeye gege bii awon ti e se n pe e ni wipe omobinrin to feran lati maa sise takuntakun yii tun ti si soobu asaraloge silu Eko.

Opopona AIT nitosi Alagbado ni soobu re naa wa,nibiti won ti n ta kirimu to n mu ara dan,kiriimu to le je ki ewa eeyan pupa jade,ose iwe to dara fun awo eeyan pupa,beeni won tun n fo ara nileese won.

Ohun to tun je ki Ile asaraloge Yeye Olukuewu yato gedegbe ni pe aye tun ti si sile fun enikeni to ba feran lati ko ise asaraloge bii oju kikun,gele wiwe,eekanna kikun ati beebee lo.

Nomba ti e le pe boya eyin feran lati lo se oge nileese won niyi 08023899837

No comments:

Post a Comment

Pages